The Cloud Of Witness

THE SEED
Therefore we also since we are surrounded by so great a cloud of witnesses, let us lay aside every weight, and the sin which so easily ensnares us, and let us run with endurance the race that is set before us. Hebrews 12:1

In athletics, whether field or track events, there are most times a large number of people that sit in the stands watching those athletes on the tracks about to participate in a race. Most time they will be cheering them up and encouraging them in order to finish the race well. The walk of faith or Christian race has been walked and ran by a number of people before us who had ran by the rules and gone through the process. Some failed while some succeeded. These are the cloud of witnesses we have. Since some have completed it successfully, we shall also complete the race successfully by the grace of God. You cannot form your rule now but you have to live by the commandment given by God Almighty. Believe in the work of Salvation done by the only begotten Son that He sent to us.

PRAYER
May I finish my race in success in Jesus name. Amen.
BIBLE READINGS: Hebrews 12:1

  AWON AJERI

IRUGBIN NAA 
Nitori naa bi a ti fi ikuukuu awosanmo ti o kun fun awon elerii to ba yii wa ka, e je ki a pa ohun idiwo gbogbo ti si apa kan, ati ese ti o rorun lati di mo wa, ki a si maa fi suuru sure ije ti a gbe ka iwaju wa. Hebrew 12:1

Ninu ere idaraya, iba se ere sisa tabi ere ori papa, opolopo igba ni ero ma po ti won a si dide duro lati ye awon ti o ba fe kopa ninu ere idaraya, ti won a ma ye won si. Opolopo igba ni won a ma ye won si ki won ki o le pari ere idaraya won, ki won si se aseyege. Opolopo eniyan ni won ti rin irin igbagbo tabi sa ere ije Kristeni, awon kan kunna beeni awon kan se aseyege, awon awon wonyi ni a npe ni Ajeri. Nitori awon kan sa ere na ti won si se aseyege, iwo naa yio sa ere naa ti iwo yio si se aseyege pelu oreofe Olorun. A ko le da ofin sile fun ra wa, sugbon a gbudo ma rin ninu ofin ti Oluwa fi lele fun wa. E gbagbo ninu ise igbala ti Omo re nikansoso ti se fun wa.

ADURA
Mo ma se aseyori ninu ere ije ni oruko Jesu. Amin.
BIBELI KIKA: Heberu 12:1

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *