The Ever Steadfast God

 

THE EVER STEADFAST GOD

THE SEED 

“The steadfast love of the Lord never ceases; his mercies never come to an end; they are  new every morning; great is your faithfulness.” Lamentations 3:22-23 ESV

The opening scripture reminds us that the Word of God is His bond.  

It means He will keep all His promises. It means that God will fulfil every prophecy He  has made. He never forgets, never fails, never falters, never forfeits His word. To every  declaration of promise or prophecy the Lord has exactly adhered, every engagement of  covenant or threatening He will make good.  

When man is faithless, God remains faithful. God was faithful with Adam and Eve even  though they sinned against Him. God was also faithful with Noah, Abraham, Isaac, Jacob,  Joseph, Moses, David, etc. 

The names mentioned are from different generations, attesting to the fact that God’s  steadfastness extends to all generations. In our present day, God is still steadfast.  Dearly beloved, as believers, we have been adopted by a Father who will never write us  off, never leave us or forsake us in our time of challenge. Even in His chastisement, He  remembers His love for us. If you are a part of God’s family by faith alone in Christ alone, then  you have a Friend who sticks closer than you can ever imagine.  

PRAYER 

O Lord, help me to remain in your steadfast love in all my situations. 

BIBLE READINGS: Lamentation 3:22-32 

OLORUN TO DURO SINSIN LAE 

IRUGBIN NAA 

“Aanu Olorun ni ti awa ko parun tan, nitori ironu-aanu re ko ni opin. Otun ni li orowuro,  titobi ni otito re.” Ekun Jeremiah 3:22-23 

Ese Bibeli ti a ka ni ibere ran wa leti wipe Oro Olorun ni edidi re. 

O tumo si wipe yio mu gbogbo ileri re se, o tun jasi wipe Olorun yio mu gbogbo asotele  re se. ko je gbagbe, kii se aseti bee si ni, kii kuna, kii padanu oro re. Olorun je olotito si gbogbo  ileri ati oro asotele ti o ti so. Gbogbo majemu ati ipinnu re, ni yio mu se. 

Nigbati eniyan je alainigbagbo, Olorun je olotito, Olorun se olotito si Adamu ati Efa, bi o  tile je wipe won dese. Bakan naa, Olorun je olotito si Noa, Abrahamu, Isaaki, Jakobu, Josefu,  Mose, Dafidi ati bee bee lo. 

Awon oruko ti a da wonyi ni a mu jade lati orisirisi iran, eyi ti n jeri si otito wipe iduro  sinsin Olorun wa lati iran de iran. Titi di akoko yii, Olorun duro sinsin. 

Olufe owon, gege bi onigbagbo, a ti sowa domo lowo Baba wa ti ki yio ja wa kule lae, ti ki  yio fi wa sile tabi ko wa sile nigba iponju wa, nigba ti nwon tile n naa, o ranti ife re si wa. Bi o ba  wa lara ebi Olorun nipa igbagbo ninu Kristi nikan, nigba naa, o ni ore ti n sunmo ni ju bi o ti lero  lo. 

ADURA 

Oluwa, ran mi lowo kin le wa sibe ninu ife re ti o duro sinsin ni ipo kipo ti mo ba wa. Amin 

BIBELI KIKA: Ekun Jeremiah: 3:22-32

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *