THE GOOD SHEEP THE SEED
MAY 8 SUN 2022
“I am the good shepherd: the good shepherd giveth his life for the sheep.” Jn.10:11 KJV It is the Shepherd’s responsibility to feed the sheep, to lead the sheep, to guide the sheep and to protect the sheep. Jesus has declared this to be His work in our lives (Jn. 10: 1 – 16).
However, the sheep being led by the Shepherd have responsibilities as well. The sheep have to listen and obey his voice (verse 5). If the sheep does not obey the voice of its shepherd, it is left exposed to the wolves.
Wolves are watching the herd to see the sheep they can steal, kill and destroy. In our walk with God, we have our part to play; so does God.
We cannot play His part, and He will not play our part.
PRAYER
Father Lord, grant me the power of prevailing prayer everyday of my life In Jesus Name Amen. BIBLE READINGS: John 10: 1-21, Ezekiel 34: 11-16
AGUTAN RERE
IRUGBIN NAA
“Èmi ni olùṣọ́-àgùntàn rere: olùṣọ́-àgùntàn rere fi ọkàn rẹ̀lélẹ̀nítorí àwọn àgùntàn.” Johanu 10:11
Ojuse oluso agutan ni lati maa bo agutan, maa dari, maa to ati lati da abo bo agutan. Jesu si ti fihan wipe eyi ni ise oun ninu aye wa. (Johannu 10:1-16)
Bi o tile je wipe agutan ti oluso agutan n dari ni ojuse tire bakan naa. Agutan naa ni lati fetisile ki o si tele ohun oluso agutan re (vs 5). Bi agutan naa ba si ko lati tele ohun oluso agutan, yio wa ninu ewu ikooko lati pa je.
Awon ikooko won n so agbo eran lati wa agutan ti won yio ji, pa ati parun. Ninu ibasepo wa pelu Olorun, awa ni ojuse tiwa, bee si ni Olorun ni ipa tire.
Awa ko le se ojuse Re, bee si ni Oun ko le ba wa se ojuse tiwa.
ADURA
Baba mi orun, loni, mo pinnu lati je agutan rere, ki ojuse re gege bi oluso agutan ki o le di pipe ninu aye mi ni oruko Jesu. Amin.
BIBELI KIKA: Johanu 10: 1-21, Ezekiel 34: 11-16