THE GOOD SHEEP THE SEED 

 

THE GOOD SHEEP THE SEED 

MAY 8 SUN 2022 

“I am the good shepherd: the good shepherd giveth his life for the sheep.” Jn.10:11 KJV  It is the Shepherd’s responsibility to feed the sheep, to lead the sheep, to guide the  sheep and to protect the sheep. Jesus has declared this to be His work in our lives (Jn. 10: 1 – 16). 

However, the sheep being led by the Shepherd have responsibilities as well. The sheep  have to listen and obey his voice (verse 5). If the sheep does not obey the voice of its shepherd,  it is left exposed to the wolves.  

Wolves are watching the herd to see the sheep they can steal, kill and destroy. In our  walk with God, we have our part to play; so does God.  

We cannot play His part, and He will not play our part. 

PRAYER 

Father Lord, grant me the power of prevailing prayer everyday of my life In Jesus Name Amen. BIBLE READINGS: John 10: 1-21, Ezekiel 34: 11-16 

AGUTAN RERE 

IRUGBIN NAA 

“Èmi ni olùọ́-àgùntàn rere: olùọ́-àgùntàn rere fi ọkàn rẹ̀lélẹ̀nítorí àwọn àgùntàn.”  Johanu 10:11 

Ojuse oluso agutan ni lati maa bo agutan, maa dari, maa to ati lati da abo bo agutan. Jesu si ti  fihan wipe eyi ni ise oun ninu aye wa. (Johannu 10:1-16) 

Bi o tile je wipe agutan ti oluso agutan n dari ni ojuse tire bakan naa. Agutan naa ni lati  fetisile ki o si tele ohun oluso agutan re (vs 5). Bi agutan naa ba si ko lati tele ohun oluso agutan,  yio wa ninu ewu ikooko lati pa je. 

Awon ikooko won n so agbo eran lati wa agutan ti won yio ji, pa ati parun. Ninu ibasepo  wa pelu Olorun, awa ni ojuse tiwa, bee si ni Olorun ni ipa tire. 

Awa ko le se ojuse Re, bee si ni Oun ko le ba wa se ojuse tiwa. 

ADURA 

Baba mi orun, loni, mo pinnu lati je agutan rere, ki ojuse re gege bi oluso agutan ki o le di pipe  ninu aye mi ni oruko Jesu. Amin. 

BIBELI KIKA: Johanu 10: 1-21, Ezekiel 34: 11-16 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *