TURNING TO GOD IN OUR STATE OF GUILT

https://the-seed-audio.s3.eu-west-2.amazonaws.com/wp-content/uploads/2024/12/17105827/second-hand-149907.mp3

THE SEED

“For all have sinned and fall short of the glory of God, and all are justified freely by his grace through the redemption that came by Christ Jesus.” Romans 3:23-24 (NIV)

Our opening Bible verse declares that “All have sinned“. Remaining in guilt does not help anyone to grow in the Lord, rather it causes setbacks and destruction. To avoid such, God has made His grace appear to all men through His Son Jesus to relieve us of all guilt. As His children we are invited to a life of freedom from guilt, we should not allow the Devil to take advantage of us through guilt but we should accept the invitation of God by turning to Him when we do anything wrong. The way out of the web of guilt is the total confession of what has been done wrong and an apology for the wrongdoing to God and the person involved. Let us understand that guilt need not burden us endlessly; rather, it can be a trigger for sincere repentance and a renewed commitment to God. The Psalmist in the book of Psalm 51 expressed this in a heartfelt plea to God, to show us how we can sincerely turn to God with our guilt, inviting God to transform his guilt-ridden heart into a vessel of purity and steadfastness. Likewise, let’s acknowledge our guilt, but not be crippled by it. Instead, we should use it as a stepping stone towards a deeper relationship with God, seeking His forgiveness and allowing His grace to free us from the chains of guilt.

BIBLE READINGS:  Psalms 51:1-10

PRAYER: Lord, let your love be the balm that soothes my guilty soul and leads me into the light of your forgiveness in Jesus’ name.

Tuesday, December 17, 2024

PÍPADÀ SI ỌDỌ ỌLỌ́RUN NÍNÚ IPÒ ẸBÍ WA

IRUGBIN NAA

“Gbogbo ènìyàn ní o sa tí ṣẹ tí wọ́n sí ti kuna ògo Ọlọ́run; Àwọn ẹniti a nda lare lọ̀fẹ́ nípa oore-ọfẹ rẹ̀, nípa ìdáǹdè tí ó wa nínú Kristi Jésù” Romu 3:23-24

Ẹsẹ Bibeli wa ti a ṣì, nkede pe “Gbogbo eniyan ti ṣẹ.  Wíwà nínú ẹ̀bi kò ran ẹnikẹ́ni lọ́wọ́ láti dàgbà nínú Olúwa, kàkà bẹ́ẹ̀ ó ń fa ìfasẹhin àti ìparun. Láti yẹra fún irú nkan bẹ́ẹ̀, Ọlọ́run  ti jẹ́ kí oore-ọ̀fẹ́ Rẹ̀ farahàn fún gbogbo ènìyàn nípasẹ̀ ọmọ Rẹ. Jesu láti mú gbogbo ẹbí ẹ̀ṣẹ̀ kúrò.  Gẹ́gẹ́ bí ọmọ rẹ̀, a pè wá sí ìgbé ayé òmìnira kúrò lọ́wọ́ ẹ̀bi, a ko gbọ́dọ̀ jẹ́ kí èṣù gba àǹfààní wa, nípasẹ̀ ẹ̀bi ẹṣẹ. Ṣùgbọ́n ́ a gbọ́dọ̀ gba ìpè Ọlọ́run nípa yíyí padà sọ́dọ̀ Rẹ̀ nígbà tí a bá ṣe ohunkóhun tí kò tọ́.  Ọ̀nà lati kúrò nínú ìdẹkùn ti ẹbi ẹ̀ṣẹ̀ ni ijẹwọ lapapọ ti ohun ti a ti ṣe aṣiṣe ati itọrọ idariji fun aiṣedede ti a ṣe si Ọlọrun ati ẹni ti o kan ti a ṣẹ sì. Ẹ jẹ́kí a loye pe ẹbi ko nilo lati jẹ́ ẹrù ailopin fun wá;  dipo eyi ó le jẹ okunfa fun ironupiwada tootọ ati isọdọtun ifara ẹni jini si Ọlọrun. Onísáàmù nínú ìwé  Sáàmù ikọkanleladọta  fi èyí hàn nínú ẹ̀bẹ̀ àtọkànwá sí Ọlọ́run, láti fihàn wá bí a ṣe lè yíjú sí Ọlọ́run tọkàntọkàn pẹ̀lú ẹ̀bi wa; nípa  pipe Ọlọ́rún láti yí ọkàn wa, tí ó kùn fún ẹ̀bi ẹṣẹ padà sí ohun èlò mímọ́ àti ìdúróṣinṣin.  Bákan náà, ẹ jẹ́ kí a jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wa, ṣùgbọ́n kí a má ṣe sọ wá di aláìlera nipa rẹ̀.  Dipo eyi o yẹ ki a lo o bi igbesẹ si ọna àṣepọ ti o jinlẹ pẹlu Ọlọrun, ti n wa idariji Rẹ ati gbigba ore-ọfẹ Rẹ laaye lati tu wa sílẹ̀ kuro ninu awọn ẹwọn ẹbi. 

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 51:1-10

ADURA: Oluwa Jẹ ki ifẹ Rẹ jẹ òróró ti o tu ẹbi ọkàn mí lára, jẹ ki o mu mi lọ si imọlẹ idariji Rẹ ni orukọ Jesu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *