Understanding Satan

THE SEED
“There hath no temptation taken you but such as is common to man: but God is faithful, who will not suffer you to be tempted above that ye are able” 1 Corinthians 10:13

First of all, we must understand there’s Satan. He’s clever, he’s relentless, he’s vicious, he’s way out of your league and mine. Far more powerful than any of us can imagine. He’s likened to a roaring lion, prowling around, seeking someone to devour. He will show you no mercy, but he’s clever. He’s compared to an angel of light, masquerading as something enticing and beautiful.
Satan chooses carefully those he would personally attack. Satan is not omnipresent; as a created being he can only be one place at a time. That’s why elsewhere in scripture the enemy is heard speaking indirectly through demons and human instruments. Satan will often tempt you where you are the weakest, but he will also tempt you where you are the strongest. That’s what Satan did with Jesus; he tempted Him in an area Jesus knew He was strong. Everyone of us has been gifted by God. We have unique strengths and abilities that we can either use for God’s glory or misuse for our own gain. Satan will fire his missiles of temptation your way, but God is faithful! You can have faith to stand with the invincible weapon of God’s word at work in your life!

PRAYER
Satan, I resist you in my life, in my finances, career, family, relationship, home, business, and every aspect of life in Jesus name

BIBLE READINGS: Revelations 12

NINI IMOYE NIPA SATANI

IRÚGBÌN NÁÀ

“Ko si idanwo kan ti o tii ban yin, bikose iru eyiti o mo niwon fun enia: sugbon olododo li Olorun, eniti ki yio je ki a dan yin wo ju bi enyin ti le gba” I Korinti 10:13

Lakoko, a gbodo ni oye wipe satani wa. O ni ogbon, kii simi, a maa rin kiri, o ni oye ohun gbogbo ju wa lo, osi lagbara ju bi a ti lero lo. Afi we kiniun ti n bu ramuramu, o rin kaakiri, o n wa eniti yio pa je. ko ni aanu sugbon o ni arekereke, a fi we angeli imole, o fi ara re se ohun ti o wuni tabi ti o rewa. Satani mo awon ti o fe paje. satani ko wa ni ibi gbogbo. Gege bi eda Olorun, ko see se fun un lati wa ni ibi gbogbo leekan naa, idi niyi ti ota fi maa nlo awon emi esu ati eniyan. Opo igba ni satani maa n dan ni wo nigba ti aare ba mu wa, sugbon yio tun dan wa wo nigba ti okan wa ba le. Ohun ti satani se pelu Jesu niyi, o dan an wo ni ibi ti Jesu mo pe on lagbara. Gbogbo wa ni a fun ni ebun lati odo Olorun. A ni agbara ati okun ti o yato ti a le lo fun ogo Olorun tabi lati sii lo fun ere tiwa. Satani maa n fi awon nkan idanwo si ona re, sugbon Olorun je Olotito! Iwo le ni igbagbo lati duro pelu oro olorun ti nse ohun ija ti a ko fi oju ri tii sise ninu aye re!

ADURA

Satani, mo ba o wi ninu aye mi, ninu isuna mi, ise, ebi, igbeyawo, ile, oko owo, ati gbogbo ona aye mi ni oruko Jesu. Amin

BIBELI KIKA: Ifihan 12

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *