VICTORY OVER DISEASES


VICTORY OVER DISEASES

THE SEED 

“And said, If thou wilt diligently hearken to the voice of the LORD thy God, and wilt do  that which is right in his sight, and wilt give ear to his commandments, and keep all his  statutes, I will put none of these diseases upon thee, which I have brought upon the  Egyptians: for I am the LORD that healeth thee.” Exodus 15:26  

The scripture has given us insight on how the children of God can avoid all forms of  diseases and ailments. They are ‘to diligently hearken, do right, pay attention, and keep His  Words’.  

First of all, to diligently hearken is to listen to the word of God with the aim of putting it  to action.  

Secondly, doing right means acting on the word of God the way He wants it to be done.  Thirdly, paying attention is to listen to God and memorise the details.  

Lastly, keeping his word is to make a conscious effort to retain the word in our heart  and mind. These four keys work hand in hand.  

Dearly beloved, Jesus Christ has made things easy for us to please God by giving us His  grace and the Holy Spirit. Hence, it is easy for us as Christians to win the war against diseases  and sicknesses.  

PRAYER 

Oh Lord, grant me the grace to hearken diligently unto Your word. Amen.  BIBLE READINGS: Mark 5:21-34, Luke 10:19 

ISEGUN LORI ÀÌSÀN 

IRÚGBÌN NÁÀ 

“O sí wipe, Bi iwọ o bá tẹtisilẹ gidigidi sí ohun OLUWA OLORUN rẹ, ti o bá sì e èyítí o tọ li  oju rẹ̀, tí iwọ o bá sì fetí sí òfin rẹ, ti iwọ o bá sì pa gbogbo aẹ rẹ mọ́, emi kí yíó si fi ọkàn  nínú àrùn wọnni ti mo muwa sára àwọn Egipiti sí ọ lára: nitori emi li OLUWA tí o mu ọ lara da.( Ẹkisodu 15 :26) 

Ẹkọ kíkà wá fún wà ní Itoni nipa bi awon ọmọ Ọlọrun e lè wà lí àìní àwọn àrùn tabi  awọn àìsàn. Wọn gbọdọ farabale lati e èyí tí o tọ, latí fiyesi ati láti pa ọrọ Rẹ mọ.  Èkíní, láti farabale, ní pe ki a gbọ ọrọ Ọlọrun nipa kí a fi sí ojúe. 

 Èkejì, íe èyí tí o tọ, tumọ sí mímu ọrọ Olọrun wá sí ojúe gege a tí fẹ kí a e.  Ìkẹta lati fiyesi, tumọ sí fi fi etí sí ọrọ Olọrun kí a sì kọ ọ́9 ní ẹsẹ é.  Nipari, pipa ọrọ Olọrun mọ ní pe ki a sa ipa lati ri pé ọrọ náà rí ayé ní ọkàn wá, kí a sì pa  a mo. Awọn kòkòrò merin yi, máa niẹ papọ lai yá ará wón. 

 Olufẹ Jesu Kristi ti mu ohun gbogbo rọrun fún wá, láti lè tẹ lọrùn nípa fífún wa ni ore-ọfẹ ati emi mímó. Nitori idi eyi o rọrun fún wá gẹgẹ bí Kristẹni láti lè ẹgun àrùn ati àìsàn. 

ADURA Oluwa fún mi ni ore-ọfẹ lati farabale gbo ọrọ rẹ Amin.  

BIBELI KIKA: Mark 5:21-34, Luke 10:19 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *