Vision

THE SEED
“And he brought him outside and said, “Look toward heaven, and number the stars, if you are able to number them.So shall your offspring be.” Genesis 15:5

The eyes are created for sight. However, there is a limit to what man can see on his own. Absolute reliance on the human sight cannot capture the full image of one’s destiny. The highest dimension of vision any believer can possess is in what he sees through the eyes of God. This kind of vision only comes by divine revelation. God told Abraham to look at the number of the stars, for that would be the measure of his offsprings. At this time, Abraham had no children, yet he believed. God gave him a new vision that transcended his immediate situation.As far as man sees through the eyes of God, so he becomes. It is through vision that we see the predetermined plans of God for our lives. Anyone who cannot see beyond his or her immediate circumstances into a higher revelation cannot fulfill destiny. Brethren, what is God showing you about your life? Establish it in the Word of God and trust the process as God makes this year a year of fulfillment for you.

BIBLE READING: Genesis 15: 1-21

PRAYER: My Father, please open my eyes to see your plans for me, so that I may walk in your covenant of blessings all the days of my life. Amen.

IRAN

IRUGBIN NAA
“Olúwa sì mú Abramu jáde sí ìta ó sì wí fún un pé, “Gbé ojú sókè sí ọ̀run kí o sì ka àwọn ìràwọ̀ bí ó bá ṣe pé ìwọ le è kà wọ́n.” Ó sì wí fun un pé, “Nítorí náà, báyìí ni irú-ọmọ rẹ yóò rí.” Genesisi 15:5

A da oju fun iran. Sugbon iwonba ni oun ti oju wonyi le ri. Eni to ba gbekele oju ara re nikan ko le ri aworan emi. Iran to ga julo fun onigbagbo ni oun ti o ri lati ipase oju Olorun. Oluwa lo si n fi iru iran yii han ni. Oluwa so fun Abrahamu ki o wo iye awon irawo, nitori bee ni iru-omo re yio ri. Ni akoko yii, Abraham ko tii ni omo, sibe o gbagbo. Olorun fun un ni iran eyi ti o ju ipo ti o wa ni akoko yii lo.Ìwòn ohun ti a ba ri nipase Emi Olorun ni ma n so ohun ti a o je. Ninu iran ni a ti le ri eto Oluwa ti O ti pinnu fun aye wa. Enikeni ti ko ba le riran koja oun ti on la koja lowolowo ki o si ni ifihan orun, ko le mu ipinnu Olorun se. Ará, kinni Oluwa n fi han o nipa aye re? Fi ìdí re mule ninu oro Olorun, ki o si gbekele ilana re fun o, ki o le ni ìmúse ninu odun yii.

BIBELI KIKA: Genesisi 15: 1-21

ADURA: Baba Mi, jowo si oju emi mi ki n le ri ètò Re fun mi, ki emi le ma rin ninu majemu Ibukun Re nigbogbo ojo aye mi. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *