We Have A Ministry Of Reconciliation

THE SEED
“So Jehoshaphat dwelt at Jerusalem, and he went out again among the people from Beersheba to the mountains of Ephraim, and brought them back to the Lord God of their fathers.” 2Chronicles 19:4 NKJV

Bringing people back to the Lord is our core duty in Christ. This should be achieved using everything we have including our positions and affluence at home, at work and in our community. God is always in search of a man or people like King Jehosaphat that will live to raise the banner of righteousness calling others that are yet to know God, reconciling the ones that have gone astray from God and encouraging the weak and the feeble in faith to keep going. When Jehosaphat became King over Judah, he took up the challenge to use his position to bring his people back to God. He didn’t just wish for it but he took practical steps to reform the broken systems within Judah. What is your plan to bring the people around you to God? What steps are you taking? You might not be a king or highly placed individual in your environment but what about your own little space in your home as a mother, father and children, in your family with your parents and siblings, with your friends and co-workers? Honestly, God has given every one of us adequate space filled with people that needs to be reconciled back to Him. Be encouraged to plan and take practical steps to reconcile as many people in your space back to God.

BIBLE READING: 2Chronicles 19:4-11

PRAYER: Lord Jesus, please give me the courage to reconcile my people who have not yet known you back to you. Amen

A NI ISE IRANSE ILAJA

IRUGBIN NAA
Jehoṣafati si joko ni Jerusalemu, o si tun jade lọ lãrin awọn ènìyàn lati Beerṣeba si òke Efraimu, o si mu wọn pada tọ̀ Oluwa Ọlọrun awọn baba wọn wá. 2 Kíróníkà 19:4

Mimu awọn eniyan pada si ọdọ Oluwa jẹ iṣẹ pataki wa ninu Kristi. Eyi ni a gbudo se nipa Lilo ohun gbogbo ti a ni pẹlu ipo ati ọrọ wa ni ile, ni ibi iṣẹ ati ni agbegbe wa. Ọlorun máa ń wá ọkùnrin tàbí àwọn èèyàn bíi Ọba Jèhósáfátì tí yóò wà láàyè láti gbé àsíá òdodo sókè tí yóò máa pe àwọn mìíràn tí won ko tíì mọ Ọlorun, mimu àwọn tí won ti ṣáko lọ wa si odo Ọlorun tí won sì mu awon aláìlera ninu igbagbo lokan le Lati ma a tẹsiwaju laisi idiwọ. Nígbà tí Jèhósáfátì di Ọba Júdà, ó bẹ̀rẹ̀ sí í lo ipò rẹ̀ láti mú àwọn èèyàn rẹ̀ pa dà sodọ̀ Ọlorun. Kò kàn ro o lasan ṣùgbon ó gbé àwọn ìgbésẹ̀ láti ṣàtúnṣe àwọn ilana ti o ti bàje ni Júdà. Kini ero rẹ lati mu awọn eniyan ti o wa ni ayika rẹ wa si ọdọ Ọlọrun? Awọn igbesẹ wo ni o n gbe? O le ma jẹ ọba tabi ẹni ti o wa ni ipo giga julọ ni agbegbe rẹ ṣugbọn kini ipa aaye kekere tirẹ ni ile rẹ gege bi iya, baba ati awọn ọmọde, ninu ẹbi rẹ pẹlu awọn obi ati awọn arakunrin rẹ, pẹlu awọn ọrẹ ati alabaṣiṣẹpọ rẹ? Nitootọ, Ọlọrun ti fun olukuluku wa ni ore-ofe Lati mu awon eniyan pada sọdọ Rẹ. Gbiyanju Lati pinnu, ki o si gbe igbesẹ ki o si mu awon ènìyàn pada sodo Ọlọrun.

BIBELI KIKA: – 2 Kíróníkà 19:4-11

ADURA: Jesu Oluwa, jowo fun mi ni igboya lati mu awon eniyan ti ko mo o pada si odo Ọlorun.Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *