What Level Are You?

THE SEED

“But there are some of you who do not believe.” For Jesus knew from the beginning who they were who did not believe, and who would betray Him.” John 6:64 NKJV

To all of us called Christians, that claim to be walking with God, we need to establish our conviction that God did not release His only Son, Jesus, to die the criminal death on the cross
just for us to know the truth, but still allow ourselves to walk in self-inflicted inadequacies that manifest through disobedience and indiscipline, that often takes us away from the love of Christ. God intends to empower us to have divine knowledge through Jesus that will enable us to run our race victoriously. Jesus said “ye shall know the truth and the truth shall set you free!”
God’s intention can only be fulfilled when we do not stop at knowing the truth alone but take a step further to believe and walk in the truth. We can’t afford to know the truth and still live our lives around the deceit of unbelief. It’s a dangerous ground to tread on.

PRAYER

Lord Jesus, help me to live my life in the path of truth. Amen

BIBLE READINGS: John 6:60-69

 IPELE WO NI O WÁ?

IRÚGBÌN NÁÀ

“Ṣugbọn awọn kan wà ninu nyin ti kò gbagbọ́. Nitori Jesu mọ̀lati ìbẹrẹ wá ẹniti nwọn iṣe ti ko gbagbọ́, ati ẹniti yio fi on hàn.” John 6:64 BM

Sí gbogbo wa ti a pe loruko Kristẹni, ti a si n sọ wipe a n ba Ọlọrun rin, a nilati fi ìdí ìdánilójú mulẹ pe Olorun ko ran ọmọ rẹ kan ṣoṣo Jesu, lati wa ku iku ọ̀daran lori igi agbelebu
nitori ki a le mọ òtítọ sugbọn sibẹ ki a si gba ara wa láàyè láti ma rìn nínú aiṣedede, eyi ti o nfarahàn ninu àìgbọràn ati ailẹkọ, ti won ma n fawa kuro ninu ifẹ Kristi. Ero Ọlọrun ni lati fún wa lagbara ki a le ni òye orun nipasẹ Jesu, eyi ti yíò ràn wá lọwọ láti sa èrè ìje wa laasayọri. Jesu wipe “eyin yíò mo òtítọ, òtítọ yíò sì so yin di òmìnira”. Ọrọ Olorun yìí ni o le di mimuṣe nigbati a bá ṣetan lati mọ òtítọ, ti a sì gbé ìgbésẹ síwájú síi lati gbagbọ ati láti rìn nínú òtítọ. A kò le ṣe ijafara nipa mimọ òtítọ, ki a tun ma gbe ìgbé ayé itanjẹ eyiti ainigbàgbọ́. Eyi jẹ ọna ti o léwu láti rin.

ÁDÙRÁ

Jesu Oluwa, jowo ranmi lọwọ lati gbe ìgbé ayé tí òtítọ ndárí. Amin.

BIBELI KIKA: John 6:60-69

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *