THE SEED
“Put on the whole Armour of God, that ye may be able to stand against the wiles of the devil.” Ephesians 6:11
Spiritual clothing is our protection as the Bible calls it in the text. The armour consists of: The belt of truth, the breastplate of righteousness, the Gospel boots of peace, the shield of faith, the helmet of salvation, the Sword of the Spirit – The Word of God and Prayer. So, when we see this reinforcement, we really see that what we are putting on is Jesus Himself. His personality dresses us and safeguard us from the wiles and arrows of Satan. So, when we get up every day, we put on our Armour and pronounce that we have Jesus in us. Truth, uprightness, harmony, confidence, salvation, The Word. As Christians, we should be cautious, on the alert, and completely wearing our armour and open our mouths strongly and spread the Gospel. Boldness is essential if we want to fight the good fight of faith with true success.
PRAYER
I declare victory and good success as the armour of God on me is my safeguard in Jesus Christ.
BIBLE READINGS: Ephesians 6
IHAMORA OLORUN
IRUGBIN NAA
“E gbe gbogbo ihamora Olorun wo, ki eyin kio le koju ija si arekereke esu” Efesu 6:11. Aso ti emi ni aabo wa gege bi bibeli ti toka si. Awon oun ti o wa ninu ihamora noni: Amure otito, igbaya ododo, bata ihinrere ti alaafia, apata igbagbo, asibori igbala, ida emi- oro Olorun ati adura ni igba ti a ba ri gbogbo eyi, ao ri wipe Jesu gangan ni a gbe wo. O si daabo bo wa lowo ofa esu. Nitorina, nigba ti a ba dide lojojumo, a ni lati gbe ihamora Olorun wo a o si maa so wipe Jesu wa ninu wa. Otito, isododo, irepo, igboya, igbala ati oro. Gege bi onigbagbo, a ni lati maa sora, ki a wani imurasile, ki a gbe ihamora wo ki a si la enu wa lati so ihinrere. Igboya se Pataki ti a fe ja ija rere ti igbagbo pelu aseyori.
ADURA
Mo pase isegun ati aseyori gegebi ihamora Olorun lara mi, oun si ni aabo ni nu Jesu Kristi
BIBELI KIKA: Efesu 6