Yielding To The Call

THE SEED
“I have not come to call the righteous, but sinners to repentance.” Luke 5:32 NIV

Sin enslaves, causes wretchedness, and weakens. Our heavenly Father sent His Son to die on the cross for wretched sinners. His blood purges the soul and cleanses out all the diseased states. A sinful way of life may not be one’s desire, as circumstances might have led us to live a life of captivity to the devil. However, there is a choice for us as a way out of the mess and that is why God sent His Son to die for us and to save us.He promised to give rest to the weary soul, bless the poor and needy, remove oppression and pardon every sin once you confess. Decide to change, break ties with the devil and receive grace and abundant life. Jesus said, All that the Father gives me will come to me, and whoever comes to me I will never cast out.

BIBLE READING: Luke 5:27-32

PRAYER: Lord, open my inward ear to hear your call and let me rejoice at the sound of your voice. Amen

GBIGBA IPE NAA

IRUGBIN NAA
“Emi ko wa lati pe awon olododo, bikose awon elese si ironupiwada.” Luku 5:32

Ẹ̀ṣẹ̀ ń sọni di ẹrú, ó ń fa ìbànúje, ó sì ń fa irẹ̀wẹ̀sì. Baba wa ọrun ran Ọmọ Rẹ lati ku lori agbelebu fun awọn ẹlẹṣẹ ti o buruju. Ẹjẹ rẹ wẹ ọkàn o si fo gbogbo Arun mo. Ọ̀nà ìgbésí ayé ẹleṣẹ̀ lè má je ìfe okan ẹni, gege bí àwọn idojuko se lè mú wa gbé ìgbé-ayé ese ki o fawa sí Inu igbekun esu. Sibẹsibẹ, a ni ore-ofe lati yan ọna ti yio mu wa kuro ninu igbekun. Idi niyi ti Ọlọrun fi ran Ọmọkunrin Rẹ lati ku fun wa ati lati gba wa la.O ṣe ileri lati fi isinmi fun ọkàn ti o rẹwẹsi, bukun awọn talaka ati alaini, yọ inilara kuro ati dariji gbogbo ẹṣẹ ni kete ti o ba jẹwọ. Pinnu lati yipada, fọ awọn asopọ pẹlu eṣu ki o si gba oore-ọfẹ ati iye ayeraye. Jesu wipe, Gbogbo ohun ti Baba fi fun mi, yio wa sodo mi, ati eniti o ba si tọ̀ mi wá, emi kì yio ta a nu.

BIBELI KIKA: Lúùkù 5:27-32

ADURA: Oluwa, ṣi eti inu mi lati gbọ ipe rẹ, jẹ ki n yọ̀ si ohun rẹ. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *