A LIGHT IN THE DARK
THE SEED
MAY 20 FRI 2022
“And the light shineth in darkness; and the darkness comprehend it not”. John 1: 5 The book of John uses the image of light to help explain who Jesus is. God created the world in the beginning and later sent his only Son (Jesus) to save it, because it was broken by sin and death. When Adam and Eve disobeyed God in the garden of Eden, they brought this curse on all of God’s creation (Genesis 3). The world that God once called good has since been afflicted with conflict, isolation, sickness and grief. And sin has estranged us from the God who created us.
Our sin continually forms a barrier between us and our creator. Maybe as you are reading this devotional message you are feeling the effect of sin in your life, perhaps something has happened that has left you feeling lost or confused or maybe you feel as if you are gripping in the dark, looking for a light to guide your way. The Bible promises that the darkness you may be experiencing in any way or form can never overcome the light of Christ. Like a lighthouse on a rocky shore, Jesus offers us hope and a clear path to God. There is no sin or enemy that is powerful enough to snuff out the light of God. He will always be victorious. If we place our faith in Him, He will invite us to share in His light and victory.
PRAYER
Lord, give me the eyes to see your light that shines in the dark places around me. AMEN BIBLE READINGS: Matthew 6: 22-23, Acts 26: 16-18, I The. 5:4-5
IMOLE LARIN OKUNKUN
IRUGBIN NAA
“Imole naa si n mole ninu okunkun; okunkun naa ko si bori re”. Johanu 1:5. Iwe Johanu lo aworan imole lati se alaye eni ti Jesu nse. Olorun da aye ni atetekose, lehin eyi o ran omo re kan soso lati gba a; nitoripe a ba aye naa je lati owo ese ati iku. Nigbati Adamu ati Efa se aigboran si Olorun ninu ogba Edeni, won mu egun yi wa sori gbogbo eda Olorun.( Genesisi:3). Aye ti Olorun pe ni daradara nigbakan ri, wa di ohun ti a nfi ija, isodahoro, aisan ati ija da loro. Ese sa ti ya wa nipa kuro lodo Olorun wa.
Nigbagbogbo ni ese je idena larin awa ati eleda wa. Boya o nka iwe ajumoka ojojumo yi lowo; o si ni imolara nipa ese ninu aye re: tabi ohun kan sele si o, ti o fi o sinu iporuru, tabi ti o dabi eniti o wa ninu okunkun; ti o nwa imole fun itoni.
Awon ileri inu Bibeli fi ye wa pe, iriri inu okunkun ti o nla koja l’ona kan tabi omiran, ko le bori imole Kristi; o dabi ile ti o ni imole lori apata eti odo, Jesu fun wa ni ireti ati ipa ona ti o ye kooro si odo Olorun.
Kosi ese tabi ota bi o ti wu ko lagbara, ti o le pa ina Olorun. Ao maa segun nigbagbogbo, ti a ba ni igbagbo ninu Re yio pe wa lati je alabapin ninu imole ati isegun Re. ADURA
Oluwa fun mi ni oju lati ri imole ti o ntan ni ibi okunkun ayika mi. Amin
BIBELI KIKA: Matthew 6: 22-23, Acts 26: 16-18, I The. 5:4-5