THE SEED
“He, that being often reproved hardeneth his neck, shall suddenly be destroyed, and that without remedy.” Proverbs 29:1
What are those things that people have been advising you to correct, try to listen, ponder on it, and begin to make necessary corrections in line with God because He, that being often reproved that hardeneth his neck, shall suddenly be destroyed, and that without remedy. The little bad behavior that your spouse, boss, colleague, family members and neighbours have been telling you about can either make or mar you, if not given cognisance or corrected. King Saul was rejected by God while David was chosen as replacement. See the way he tore the cloth of the servant of God while King David tore his own cloth and in sober reflection through out when he was informed of his wrongs. It is dangerous when God sends people to a person for a change of character, habit, or lifestyle and he or she keeps giving excuses. We must check ourselves today and adjust all our wrong doings before Him.
BIBLE READING: 2 Samuel 12:15-18
PRAYER: May we not use our hands to undo ourselves in Jesus Mighty Name. Amen.
RE ARA RE SILE NIGBA TA BA N BA O WI
IRUGBIN NAA
Ẹniti a ba mbawi, ti o ba warun ki, yio parun lojiji, laisi atunṣe.Òwe 29:1
Kí ni àwọn nǹkan won yẹn tí àwọn èèyàn ti ń gbà o nímoràn láti ṣàtúnṣe, gbìyànjú láti gbo, ronú lé e lórí, kí o sì be re sí í ṣe àwọn àtúnṣe tó yẹ ní ìbámu pelú Ọlorun nítori eni ti a ba n bawi nigbagbogbo ti o warun ki,yóò parun lójijì, àti pé laisi atunse. Iwa buburu kekere ti ọkọ rẹ, ọga, ẹlẹgbẹ rẹ, awọn ẹbi ati awọn aladugbo ti won ba o wi fun le tun aye re se tabi se o ni jamba, ti Iwo ko ba kawon si. Ọlorun kọ Saalù Ọba síle o si fi Dáfídì ro pò re. Iwo wo bí Saalu ṣe fa aṣọ ìránṣe Ọlorun ya atí bi Dáfídì Ọba fa aṣọ ara re ya ni iporuru okan nígbà tí won so fun wipe o se asise nla. Ó je oun ti o léwu nígbà tí Ọlorun bá rán àwọn èèyàn si ẹnì keni láti yí ìwà re pa dà, àṣà re tàbí onà ìgbésí ayé re tó sì ń se awawi. A gbọdọ ṣayẹwo ara wa loni ki a tun gbogbo awọn iṣe aitọ wa ṣe niwaju Rẹ.
BIBELI KIKA: 2 Sámúelì 12:15-18 .
ADURA: Ki a ma fi owo wa yi ara wa pada l’oruko Jesu Alagbara. Amin.