BEING A SWEET SAVOUR OF CHRIST

BEING A SWEET SAVOUR OF CHRIST

THE SEED

“For we are unto God a sweet savour of Christ, in them that are saved, and in them that perish.”  2 Corinthians 2:15 KJV

As followers of Jesus, our lives are meant to reflect His love and character to the world. Just as Christ’s sacrifice on the cross was a sweet-smelling offering to God, our daily walk should be a pleasing fragrance to Him. A life lived in love, kindness, and obedience testifies of His goodness to both believers and unbelievers. When we walk in the fruits of the Spirit  love, peace, joy, patience, gentleness, and self-control  we carry the fragrance of Christ into homes, workplaces, and communities. This fragrance has power: it draws people to Jesus and glorifies God. God wants us to live in such a way that heaven is pleased and the world encounters Jesus through us. A life that reflects Christ becomes a living fragrance that pleases God.

 

BIBLE READINGS:  2 Corinthians 2:14–17

PRAYER: Lord, let my life always be a sweet fragrance unto You, drawing others to Christ. Amen.

 

JÍJẸ́ ÒÓRÙN DÍDÙN KRISTI

IRUGBIN NAA

Nítorí òórùn dídùn Kristi ni àwa jẹ́ fún Ọlọ́run, nínú àwọn tí a ń gbàlà àti nínú àwọn tí ó ń ṣègbé. – 2 Korinti 2: 15

Gege bi omolehin Jesu, aye wa gbodo je afihan ife ati iwa Re si gbogbo aye. Gege bi ẹbọ Kristi lori igi agbelebu se je oorun didun si Olorun, irin wa lojojumo gbodo je oorun didun si i. Aye ti a gbe ninu ife, isoore ati igboran máa n jeri didara Jesu si onigbagbo ati alaigbagbo. Nigba ti a ba rin ninu eso ti Emi, awa yóò mu oorun didun yi wo inu ile wa, ibi ise wa ati awujo wa. Ooorun yii lagbara: o ma n fa awon eniyan wa si odo Jesu, yóò si fi ogo fun Olorun. Olorun fe ki a gbe igbe aye ti yóò mu ki inu orun dun si wa, ti awon eniyan yóò ba Jesu pade nipase wa. Aye ti o fi Kristi han ni n jẹ́ oorun didun ti si n wu Olorun.

 

BIBELI KIKA: 2 Korinti 2: 14-17

ADURA: Oluwa, je ki aye mi je oorun didun si o, eyi ti n fa awon eniyan wa si odo Kristi. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *