CAN’T DO IT ALONE
THE SEED
“Trust in the LORD with all your heart and lean not on your own understanding; in all your ways submit to him, and he will make your paths straight.” Proverbs 3:5–6 KJV
We are limited in strength, wisdom, and ability, but God is unlimited in power, knowledge, and love. Our human understanding is often insufficient to handle the weight of life. But when we lean on the Lord, He becomes our strength, guide, and help. Through Christ’s sacrifice, we’ve received access to forgiveness, grace, and divine help. No one can fulfill God’s plan alone. We didn’t create ourselves, and we can’t sustain ourselves. God knows the end from the beginning and guides us on the path He has prepared. When we depend on Him fully, we walk in peace and assurance, even in uncertain seasons. Trusting in God brings strength, clarity, and courage. Surrender isn’t weakness it’s the gateway to divine empowerment. God is our sufficiency; we were never meant to walk alone.
BIBLE READINGS: Proverbs 3:1–7
PRAYER: Lord, You are my Alpha and Omega. I cannot do anything without You. Reign in my life always. Amen.
O KÒ LÈ DÁ ṢÉ
IRUGBIN NAA
Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ, má ṣe sinmi lé òye ara à rẹ; Mọ̀ ọ́n ní gbogbo ọ̀nà rẹ,òun yóò sì máa tọ́ ipa ọ̀nà rẹ. – Iwe Owe 3: 5-6
Agbara, imo ati ipa eniyan máa n dopin; agbara Olorun nikan ni ki n dopin, bakanna ni imo ati ife Re. Oye eniyan ko ni agbara lati gbe ẹrù aye. Sugbon nigba ti a ba sinmi le Oluwa, oun yóò je agbara, itona ati iranlowo fun wa. Nipa irubo Kristi, a ti gba idariji, ore ofe ati iranlowo atorunwa. Ko si eniyan to le da ṣe ètò Olorun. Awa ko ni a da ara wa, nitorina a ko ni agbara lati pa ara wa mo. Olorun mo opin lati ibeere, yóò si to wa ni ona eyi ti oun ti pese sile. Nigba ti a ba gbekele, a wa yóò rin ninu alaafia pelu idaloju, bo ti wu ko ri. Gbigbekele Oluwa máa n mu agbara, iran to daju, pelu imo wa. Jijowo oun gbogbo kii se ailera – awa yóò gba agbara lati orun wa. Oluwa to fun wa, awa ko ni lati da rin.
BIBELI KIKA: Iwe Owe 3: 1-7
ADURA: Oluwa, iwo ni Alfa ati Omega mi. Emi ko si le se ohunkohun lai si ìrẹ. Joba ninu aye mi titi lai. Amin.