CONFIDENCE IN CHRIST

THE SEED

“Wherefore I beseech you, be ye followers of me.” – 1 Corinthians 4:16 (KJV)

Jesus commanded us to spread the gospel boldly, and confidence is vital in fulfilling this assignment. Paul could boldly tell others to follow him because he lived in alignment with God’s will. When we walk in confidence in Christ, our words carry weight, and our lives become a testimony that draws others to Him. True confidence in Christ is not pride—it’s faith in His power working through us. As followers of Christ, people should be able to look at our lives and be inspired to know and follow Jesus.

BIBLE READINGS:  Acts 4:8–20 (KJV)

PRAYER: Father, fill me with divine confidence to live as a true example of Christ, so that my life will inspire others to follow You. Amen.

 

IGBOYA NINU KRISTI

IRUGBIN NAA

Nitorina mo bẹ̀ nyin, ẹ mã ṣe afarawe mi. I Korinti 4:16

 

Jesu pase pe ki a tan ihinrere kaakiri laifoya, a nilo igboya lati se eyi. Paulu le fi igboya so fun awon eniyan lati tele on nitoripe o gbe igbe aye to wa ni ibamu pelu ife Olorun. Nigbati a ba nrin pelu igboya ninu Kristi, oro wa yoo ni itumo, aye wa yoo si kun fun eri to nmu awon eniyan sunmo Olorun. Igboya tooto ninu Kristi kii se igberega – bikose igbagbo ninu agbara Re ti nsise ninu wa. Gege bi omoleyin Kristi, awon eniyan gbodo ri aye wa, ki o si wu won lati mo Jesu ati lati tele E.

 

BIBELI KIKA: Ise Awon Aposteli 4:8-20

ADURA: Baba, fun mi ni igboya latorunwa, lati le maa gbe gege bi apeerẹ rere ti Kristi, ki aye mi le mu ki awon eniyan tele O. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *