Content In Your Own Race

THE SEED
“…let us run with endurance the race that is set before us, looking unto Jesus, the author and finisher of our faith…” Hebrews 12:1-2, NKJV

In life, competing with everybody around us when we see somebody who’s more capable, better looking or has more gifts. Rather than running our race and being OK with what our identity is, generally, we feel inferior and think, “I must meet up to their standard.” The issue with this unfortunate competition is that it’s a never-ending cycle. There will always be someone ahead of us. But, it’s a very freeing thing when you realize, “I’m not competing with you. I don’t
have to have as big a house as my neighbor to feel good about myself. I don’t have to keep up with my co-worker. I don’t have to be a certain size. I don’t have to have as many Christmas lights outside. No, I understand that I’m not in competition with my friend, my neighbor or my co-worker. Instead, I’m going to be the best me that I can possibly be.” Contentment is an attitude God can work with. When you focus on being who God made you to be and focus on running your own race, that’s when you’ll see things happen. That’s when you’ll rise up higher and position yourself for every spiritual blessing He has in store for you!

PRAYER
Father, I humbly come to You giving You all that I am. I choose to keep my eyes on You and allow You to work in my heart and mind. I declare that I am free from competition today in Jesus’ name. Amen.

BIBLE READINGS: Hebrews 12

NI ITELORUN NINU ERE IJE TIRE

“Ki a maa fi suru sure ije ti a gbe ka iwaju wa.” Heberu 12: 1-2

Ninu aye, a maa nfi agagbaga pelu gbogbo eniyan ni ayika wa nigbati a ba ri eni ti o le se ohun kan ju wa lo, tabi dara ni wiwo tabi ni ebun pupo. Dipo ki a maa sa ere tiwa ki a si ni itelorun pelu eni ti a je, a maa ro pe a ko dara to, a o si maa ro lokan wipe, “ mo gbodo da bi ti won”. ohun ti o buru nipa ifagagbaga yii nipe o je ohun ti kii ni opin. Nigbogbo igba ni eyan kan maa wa niwaju wa. Sugbon, o je ohun ti o finilokanbale nigbati o ba ri pe, “ mi o ba o
figagbaga”. Mi o ni lati ni ile to tobi bi ti aladugbo mi lati mu inu ara mi dun. Mi o ni lati sare lati ba alabasise mi. ko je dandan ki n tobi bakan. Ko je dandan ki n ni ina keresimesi pupo ni ita ile. Rara, mo ni oye pe mi o fi agagbaga pelu ore mi, aladugbo mi tabi alabasise mi. Dipo be, emi yio ri wipe mo dara ju ateyinwa lo. Itelorun je iwa ti Olorun le ba sise. Ti o ba gbaju mo ati je eni ti olorun da o lati je ki o si gbajumo sisa ere ije tire, nigba naa ni iwo yio ri awon ohun ti yio sele. Nigbana ni iwo yio ga soke, wa si wa ni ipo fun gbogbo ibukun ti emi ti O ni ni ipamo fun o.

ADURA
Baba, mo wa si odo re lati yonda ohun gbogbo ti mo je pelu iteriba. Mo pinnu lati gbe oju mi le o ati lati gba o laye lati sise ninu okan mi. Mo palase pe mo ti bo kuro ninu ifagagbaga loni ni oruko Jesu. Amin.

BIBELI KIKA: Heberu 12

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *