Wise Men Rejoice

THE SEED
“…the star which they had seen in the East went before them, till it came and stood over where the young Child was. When they saw the star, they rejoiced with exceedingly great joy. And when they had come into the house, they saw the young Child with Mary His mother, and fell down and worshiped Him…” Matthew 2:9-11, NKJV

The wise men made a trip, an impressive distance to see the incomparable King whose arrival the Bible predicted. They followed the splendid star, and when they found Him, it says they celebrated extremely. Those men were glad to such an extent that they couldn’t conceal it. What they did straightaway; they bow down and adored Him. When a wise person seeks Jesus, they are filled with indescribable joy. They are compelled to worship Him! Let that be you and me today. Let’s let the joy of the Lord fill our hearts and be reflected on our faces during the holiday season and every day of the year. Don’t allow the pressures and busyness of life steal your joy. Let those around you see that you’ve been with Jesus. Rejoice in Him, worship Him, and walk with Him in victory all the days of your life!

PRAYER
Father, I choose to be wise and seek You first. Fill me with Your joy which is strength. I set my heart and mind on You and worship You. You are the King of kings and Lord of lords in Jesus’ name! Amen.

BIBLE READINGS: Matthew 2

AWON AMOYE YO AYO NLA
“…Irawo ti nwon ti ri lati iha ila-oorun, o saju won, titi o fi wa duro loke ibiti omo-owo naa gbe wa. Nigbati nwon si ri irawo naa, nwon yo ayo nlanla. Nigbati nwon si wo inu ile, nwon ri omo-owo na pelu Maria iya re, nwon wole, nwon si foribale fun u.” Matteu 2: 9-11

Awon amoye rin irin ajo, irinajo ona jinji lati ri oba ailakawe ti Bibeli ti so nipa dide re. Won tele irawo didan naa, nigbati won si ri, o so wipe won yo gidigidi. Awon okunrin yii ni ayo to bee ti won ko le fi pamo. Nnkan ti won se lesekese; won foribale won si sin. Nigbati amoye eniyan ba nwa Jesu, won maa nkun fun ayo ailakawe. Won ri wipe o ye lati sin in! Je ki o je iwo ati emi loni. Je ki a fi aye gba ayo oluwa lati kun okan wa, ki o si ma jeyo ni oju wa ni akoko igbaye ati gbogbo ojo inu odun. Ma se jeki girigiri ati idamu aye ji ayo re. Je ki awon to wa ni ayika re ri wipe o ti wa pelu Jesu. Yo ninu re, sin in, si rin ninu isegun pelu re ni gbogbo ojo aye re!

ADURA
Baba, mo pinnu lati je ologbon ati lati koko wa oju re. Fi ayo re kun mi eyi ti nse agbara. Mo gbe okan ati aya mi le o lati sin o. Iwo ni oba awon oba ati oluwa awon oluwa ni oruko Jesu! Amen.

BIBELI KIKA: Matthew 2

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *