How To Take Your Life Back

THE SEED
“…take captive every thought to make it obedient to Christ.” 2 Corinthians 10:5, NIV

At any point do you feel like things in your day to day existence are wild? Typically, when we permit our conditions to direct our thoughts and attitudes. You could say, “Indeed, the economy is unleashing ruin on my business.” Or, “This relationship is far gone.” But today is the day to earn your life back! We live in this regular life, however as Christians, we are not restricted by this regular life. We can tap into God’s supernatural power, but it starts by making every thought line up with the Word of God. Take your life back by taking your thoughts back. Don’t allow the enemy to have access any longer. Instead, meditate on the Word of God daily and allow His truth to sink down deep into your spirit. Let His truth make you free. Today, as you take captive every thought and boldly declare His promises over your life, you are setting yourself up for victory. You are positioning yourself to receive every spiritual blessing, and you are taking your life back!

PRAYER
Father, thank You for empowering me to live in victory today. I choose to take my life back by taking captive every thought and submitting it to You. Help me live a life that is pleasing to You, Jesus, today and every day in Jesus’ name, Amen.

BIBLE READINGS: 2 Corinthians 10

ONA ATI GBA AYE RE PADA

IRÚGBÌN NÁÀ
“….. awa si ndi gbogbo ero ni igbekun wa si iteriba fun Kristi.” 2 Korinti 10:5

Nje ni ikorita kan, o ro wipe ohun ni iwalaye ojojuumo re je isoro? Nigbati a ba gba ipo wa laye lati dari ero ati iwa wa. Iwo le so wipe,” Nitooto, eto isuna yii n ba oko owo mi je.” tabi, “ibasepo yii ti baje- jina.” Sugbon oni ni ojo lati gba aye re pada! Awa n gbe ninu aye lasan, sugbon gege bi kristiani, awa o si ni ipenija ni aye lasan yii. Awa le gba ninu agbara Olorun, sugbon o bere nipa mi mu ki gbogbo ero wan i ibamu pelu oro olorun. Gba aye re pada nipa gbigba ero okan re pada. Ma se jeki ota ni aaye si o mo. Kaka bee, se asaro lori oro olorun lojoojumo ki o si je ki otito re wo inu emi re. Je ki otito re tu o sile. Lonii, bi o ti mu ni igbekun gbogbo ero ti o si kede ileri re lori aye re, iwo mu ara re le fun isegun. Iwo n fin ara re si ipo lati gba gbogbo ibukun emi, o sin n gba emi re pada!

ÁDÙRÁ
Baba, ose ti o ro mi lagbara lati gbe ninu isegun lonii, mo pinnu lati gba aye mi pada nipa mimu gbogbo ero nigbekun ati dida pada fun o. Ran mi lowo lati gbe igbe aye ti o dun mo o, Jesu, lonii ati gbogbo ojo ni oruko Jesu, Amin.

BIBELI KIKA: 2 Korinti 10

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *