How To Move On

THE SEED
“But if you do not forgive, neither will your Father who is in heaven forgive your transgressions.” Mark 11:26, NASB

God never guaranteed that life would continuously be fair. He cautions us of the exact opposite, truth be told! we are not; we as a whole settle make mistake and make terrible choices. You might have been hurt by others before, yet what’s most significant is the means by which you decide to manage that hurt. When you harbor hurts and offenses, it keeps you stuck in the past. It only causes harm in your life. If you want to move forward in joy and peace, you have to choose forgiveness. Yes, forgiveness is a choice, and it has nothing to do with the person who hurt you. Forgiveness is the choice to hand your hurts over to God and let Him make up the difference. When we choose to extend forgiveness, that’s when we choose to receive His forgiveness! Today, choose God’s way, choose forgiveness, and choose to move forward in the blessing and victory He has prepared for you!

PRAYER
Father, thank You for the gift of forgiveness. Today I open my heart and mind to You. I ask that You help me understand Your truth about forgiveness so that I can be set free. I love You and bless You today in Jesus’ name! Amen.

BIBLE READINGS: Mark 11

ONA LATI TESIWAJU

IRÚGBÌN NÁÀ
“Sugbon bi enyin ko ba dariji, Baba nyin ti mbe li orun ki yio dari ese nyin ji yin.” Marku 11:26

Olorun ko fun wa ni idaniloju wipe gbogbo igba ni nkan a maa dun ni aye. O n kilo fun wa nipa idakeji re, ki a so otito, awa gege bi eyan maa nse asise ati ipinnu ti ko dara. O seese ki awon eniyan ti se o ri, sibe eyi to se pataki julo ni ona ti o ngba lati tu ara re ninu. Nigbati o ba ti fi ogbe ati ikoro sinu okan re, o maa mu ki o ha si igba atijo. Ewu nikan ni o maa fa sinu aye re. Ti o ba fe sun siwaju ninu ayo ati alaafia, o ni lati yan lati dariji. Beeni, Idarijini je ipinnu, ko si ni nkan se pelu eni ti o se o ni ibi. Idarijini ni ipinnu lati fa edun okan re le Olorun ki o si je ki o se ojutu sii. Nigbati a ba pinnu lati na owo idariji, nigbana ni a pinnu lati gba idarji re! Loni, yan ona Olorun, yan idarijini, ki o si yan ati sun siwaju ninu ibukun ati isegun ti o ti pese sile fun o!

ÁDÙRÁ
Baba, ose fun ebun idarijini. Lonii mo si okan ati aya mi paya si o. mo beere pe ki o ran mi lowo lati ni oye nipa otito re nipa idariji ki emi le gba itusile. Mo feran re mo si fi ibukun fun o loni ni oruko Jesu! Amin.

BIBELI KIKA: Marku 11

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *