Cover Yourself With Him

THE SEED
“Clothe yourself with the Lord Jesus Christ (the Messiah), and make no provision for [indulging] the flesh [put a stop to thinking about the evil cravings of your physical nature]” Romans 13:14, AMPC

Is there something in your life that you might want to end today? Perhaps it’s a sure way of behaving, habit or terrible attitude that isn’t satisfying to God? Similarly, as Adam and Eve were uncovered in their sin and needed to be dressed in the Garden, we need to dress ourselves to protect us from sin. When you “clothe yourself” with the Lord Jesus Christ, He strengthens you against temptation. How do you clothe yourself with Jesus Christ? In the same way you
cover yourself in the natural with clothing—by putting something on. You have to daily “put on” the Word of God. You have to cover your ears by listening to the Word. You cover your eyes by watching only what is pleasing to the Lord. You cover your mouth by speaking the Word and encouraging those around you. As you cover yourself with Christ, you will be strong against temptation, and you will walk in the victory the Lord has planned for you!

PRAYER
Heavenly Father, thank You for sending Your Son, Jesus, to pay the penalty for my sins. Thank You for providing a way out of temptation so that I can stand clean before You. Help me stand strong as I cover myself with Your Word in Jesus’ name. Amen.

BIBLE READINGS: Romans 13

DAA BO ARA RE

IRÚGBÌN NÁÀ
“Sugbon e gbe Jesu Kristi Oluwa wo, ki e ma si pese fun ara lati maa mu ifekufe re se.” Romu 13:14

Ohun kan ha wa ninu aye re ti o fe fi opin si loni? Boya bi o se n wuwa, ise, tabi iwa buburu ti ko te Olorun lorun? Bakan naa, bi Adamu ati Efa ti wa ni ihoho ninu ese won ti won si nilo lati woso ninu ogba, a nilo lati wo ara wa ni ewu lati pa wa mo kuro ninu ese. Nigbati o ba fi Oluwa wa Jesu Kristi bo ara re, yio fun o lagbara lati koju idanwo. Bawo ni o se le da Jesu Kristi bo ara re? Bi ati nwo aso si ara, a ni lati maa gbe oro Olorun wo. O ni lati bo eti re nipa gbigbo oro Olorun. O ni lati bo oju re nipa wiwo awon nkan ti o mu inu Olorun dun nikan. O ni lati bo enu re nipa siso oro Olorun ati nipa gbigba awon ti o wa layika wa niyanju. Bi o ti bo ara re pelu Kristi, iwo yio lagbara lati koju idanwo, iwo yio si rin ninu isegun ti oluwa ti seto fun o.

ÁDÙRÁ
Baba wa orun, oseun ti o ran omo re, Jesu, lati ku fun ese mi. O seun to pese ona abayo kuro ninu idanwo ki emi baa le duro niwaju re ni mimo. Ran mi lowo lati duro sinsin bi mo ti nfi oro re bo ara mi ni oruko Jesu. Amin.

BIBELI KIKA: Romu 13

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *