FOOD FOR THOUGHT AMONGST BRETHREN
THE SEED
“But know this, that in the last days perilous times will come:” 2 Timothy 3:1 NKJV
Have you noticed how strange things are getting? I mean just when we think we have seen or heard it all, something stranger comes along.
Have we noticed the strange things that’s going on mostly amongst brethren in the church? Brethren are more worried about what people think about them than what God says about them. It is more difficult to learn, retain and share facts about God, than to listen, believe and spread gossip.
Brethren are short of words to express thanksgiving and request in prayer but have no trouble with what to talk about with friends. Love towards our seen neighbours is fading away and replaced with selfishness. Ideas of the world now have a place in the church. Instead of brethren motivating and influencing the world for Christ, the world is motivating and influencing children of God.
Dearly beloved of Christ, these things are not supposed to be so, take a righteous step now to make a change, beginning to think, speak, act, motivate, influence and love as a child of God.
PRAYER
Lord Jesus, help me to become spiritually sensitive to the strangeness of this time and keep me in your righteousness.
BIBLE READINGS: 2 Timothy 3:1-7
ORO TI O GB’ERO LAARIN AWON ARA
IRUGBIN NAA
“Sugbon, eyi ni ki o mo, pe ni ikehin ojo, igba ewu yio de.” II Timoteu 3:1 Nje o ti se akiyesi awon ohun ajeji ti n sele? Nigba ti a ro wipe a ti ri ohun ti o ga ju, ohun miran ti o tun ga ju eyini lo tun yoju.
Nje a ti se akiyesi awon ohun ajeji ti n sele laarin awon ara ninu ijo? Nwon a maa ro ohun ti awon eniyan nso nipa won ju ohun ti Olorun nso nipa won. O soro fun won lati ko eko, mulo ati lati ba eniyan soro Olorun, sugbon o rorun lati fetisi, gbagbo ati se eke.
Awon ara kii le so oro pupo nigba ti nwon ba ndupe tabi gba adura, sugbon won kii wa ohun ti nwon o so ti nigba ti nwon ba wa laarin awon ore. Ife si omonikeji ti di ohun igbagbe ti imotara eni nikan si ropo. Awon ohun ti aye ti wo inu ijo, dipo ki awon omo Olorun ki o yi awon eniyan aye lokan pada si Olorun, awon aye ni o nyi awon omo olorun lokan pada.
Ara mi olufe ninu Kristi, awon nkan wonyi ko dara to, e gbe igbese ododo lati se atunse nisisiyi, e bere sini ronu, soro, wuwa, se iwuri, yini lokan pada si Olorun ki o si ni ife gege bi omo Olorun.
ADURA
Jesu Oluwa, ran mi lowo ki n di eniti n fi emi funra si ohun ajeji ti akoko yii, ki o si pa mi mo ninu ododo re.
BIBELI KIKA: II Timoteu 3:1-7