STAY TRUE IN TRIALS

STAY TRUE IN TRIALS

THE SEED

“Put away your sword,” Jesus told him. “Those who use the sword will die by the sword.” — Matthew 26:52 (NLT)

At His darkest hour, Jesus refused to let pain change who He was. Even in betrayal, He showed compassion, healed a wounded man, and taught truth. Many lose their character in crisis, but Jesus remained steadfast. Our true nature is revealed not when everything is smooth but when we face pressure. The way we respond to pain, injustice, or betrayal reveals the depth of our walk with God. Jesus remained loving and forgiving to the end. Beloved, trials will come, but never let them make you compromise your identity in Christ. Let your response reflect His nature, not your emotions.

Reflection: Hard times should reveal your Christlike nature, not erase it.

 

BIBLE READING: Matthew 26:47–56

PRAYER: Father, help me to stay true to who I am in Christ, even in difficult situations. Amen.

 

DURO LOTITO NINU IDANWO

IRUGBIN NAA:

“Jesu wí fún un pé, “Fi idà rẹ bọ àkọ̀ nítorí àwọn tí ó ń fi idà pa ni a ó fi idà pa.” – Matiu 26:52

Ni wakati ti o nira julo, Jesu ko je ki irora yi eni ti Oun je pada. Pelu bi a tile dà á, O fi aanu han, o wo arakunrin ti o fi ara pa sàn, o si ko wa ni eko nipa otito. Opolopo maa nso iwa nu ninu isoro sugbon Jesu duro sinsin. Eni ti a je gangan maa n farahan ki i se nigba ti ohun gbogbo ba rorun sugbon nigba ti a ba nkoju isoro. Ona ti a ngba koju irora, iyanje tabi isote maa nse afihan bi irin wa pelu Olorun ti jinle to. Jesu ni ife, O si ndariji titi de opin. Ayanfe, idanwo a wa, sugbon ma je ki o mu o yi eni ti o je ninu Kristi pada. Je ki idahun re fi Oolorun han, ki i se imolara tire.

Asaro: Igba isoro ni o ye ko fi iwa-bi- Kristi re han, ki i se ki o párẹ́.

 

BIBELI KIKA: Matiu 26: 47-56

ADURA: Baba, ran mi lowo lati duro ni otito si eni ti mo je ninu Kristi, paapaa nigba isoro. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *