THE POWER OF SELF-CONTROL

THE POWER OF SELF-CONTROL

THE SEED

“For the grace of God has appeared that offers salvation to all people. It teaches us to say ‘No’ to ungodliness and worldly passions, and to live self-controlled, upright and godly lives in this present age.” — Titus 2:11–12 (NIV)

Self-control is a vital mark of spiritual maturity. It is the ability, through the Holy Spirit, to govern your actions and desires in the face of temptation. Grace not only saves but also teaches and empowers us to live righteously.

Daniel modelled this when he resolved not to defile himself with the king’s food. His discipline positioned him for divine favour and promotion. True self-control strengthens your testimony and opens doors of lasting honour. We live in a world that celebrates indulgence, but God’s children are called to stand firm. By His grace, we can live victoriously.

Reflection: Self-control is strength under divine influence.

 

BIBLE READING: Daniel 1:1–8

PRAYER: Lord, grant me the grace to exercise self-control and live righteously in a corrupt world. Amen.

 

AGBÁRA ÌKÓRA-ẸNI-NÍ-ÌJÁNU

IRUGBIN NAA:

“Nítorí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run tó mú ìgbàlà wà ti fi ara hàn fún gbogbo ènìyàn. Ó ń kọ́ wa láti sẹ́ àìwà-bí-Ọlọ́run àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ayé, kí a sì máa wà ní àìrékọjá, ní òdodo àti ní ìwà-bí-Ọlọ́run ní ayé ìsinsin yìí..  — Títù 2:11–12

Ìkóra-ẹni-ní-ìjánu jẹ́ àmì pàtàkì ìdàgbàsókè tẹ̀mí. Ó jẹ́ agbára, nípasẹ̀ Ẹ̀mí Mimọ́, láti ṣàkóso ìfẹ́ àti ìṣe wa nígbà ìdánwò. Oore ofe kii se lati gba wa la nikan bikose fun eko ati lati ró wa ni agbara fun igbesi aye ododo. Dáníẹ́lì ṣe afihan eyi nígbà tí ó pinnu pé oun kò ní fi oúnjẹ ọba sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́. Ìkóra-ẹni-ní-ìjánu rẹ̀ ṣí ọ̀nà sí ojú rere àti ìgbéga àtọ̀runwá. Ìkóra-ẹni-ní-ìjánu ma n mu ẹrí daju, a sìí ilekun iyi pipe. Ayé lè máa ṣe ayẹyẹ ìjà-fàrà, ṣùgbọ́n ọmọ Ọlọ́run ni a pè láti dúró ṣinṣin. Nipa oore ofe Re, awa le gbe aye isegun.

ÀṢÀRÒ: Ìkóra-ẹni-ní-ìjánu jẹ́ agbára lábẹ́ ìdarí àtọ̀runwá.

 

BIBELI KIKA: Dáníẹ́lì 1:1–8

ADURA: Oluwa, fún mi ní oore-ọ̀fẹ́ láti lo ìkóra-ẹni-ní-ìjánu, ki emi le gbe igbe aye olododo ninu aye ẹ̀ṣẹ̀ yii. Amin.

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *