The Power Of Vision

THE SEED
“Where there is no vision, the people perish: but he that keepeth the law, happy is he.” Proverbs 29:18

Vision is what we see, but it is also the way in which we see. Vision is the lens that interprets the events of our life, the way we view people and our concept of God. True Godly vision consists of foresight, insight and oversight that come from His sight. Foresight is like looking at life through a telescope. This outlook allows us to know what is ahead as it connects us to our future. Visions do not originate from man but from God. They are born when the Holy Spirit breathes upon our human spirit and infuses passion inside of us. It is this passion that gives us the energy to do what God wants us to do without giving up or getting discouraged in the midst of adversity. God and man work together in realising any vision that would be a blessing on earth. As you rise up to fulfil a vision you experience the supernatural God making provision for you and giving you all the help and support you need every step of the way. When your vision is honestly birthed by God Himself. He will be delighted to direct your steps. The most important thing to remember about your steps is that they should be found somewhere in your mission.

PRAYER
My Father and my God release upon a new vision that will change my life and generation to the glory of God in Jesus name.

BIBLE READINGS: Habakkuk 2

AGBARA IRAN

IRÚGBÌN NÁÀ

“Nibiti iran Woli ko si, enia a yapa, sugbon ibukun ni fun eniti o pa ofin mo.” Owe 29:18

Iran je ohun ti a ri, sugbon o tun je ona ti a gba rii. Iran ni ohun elo ti a gba nse itumo isele aye wa, bi a se n wo eniyan ati bi a ti se ri Olorun si. Iran nipa otito Olorun ni Afojusun,
arojinle ati amojuto ti o ti odo re wa. Afojusun dabi igba ti a ba n wo aye ninu ohun iriran ti sayensi. Eyi yio je ki a mo ohun ti mbe niwaju bi o ti nii se pelu ojo iwaju wa. Iran ko ti odo
eniyan wa, bikose lati odo olorun. Eyi a maa waye nigba ti emi mimo ba mi si wa. Imisi yii ni o maa n fun wa ni agbara lati se ohun ti Olorun fe ki a se lai saare ninu wahala. Olorun a maa ba eniyan sise po lati mu ki iran ti yio je ibukun fun aye wa si imuse. Bi o ti n ji giri lati mu iran se, iwo yio ri owo nla Olorun ti yio pese fun o, ti yio si fun o ni gbogbo iranlowo ati aduroti ti o nilo ni gbogbo igbese ti o ba gbe. Niwon igba ti iran naa ba ti odo Olorun wa. Inu Re yio dun lati to isise re. ohun pataki ti o gbodo ranti nipa isise re ni wipe o gbodo farahan ninu ilepa re.

ÁDÙRÁ
Baba mi ati Olorun mi, fun mi ni iran titun ti yio yi aye mi ati iran mi pada si ogo Olorun ni oruko Jesu. Amin.

BIBELI KIKA: Habakuku 2

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *