THE SEED
“If a man therefore purge himself from these, he shall be a vessel unto honour, sanctified and meet for the master's use and prepared unto every good work.” 2 Timothy 2:21.
A vessel of honor is an instrument utilized by God to ensure that humans experience His goodness, love and favor and ultimately salvation. God desires to use
worthy, sanctified vessels to achieve His aim. As human beings in our various households, we desire to use clean vessels in the form of utensils to eat and drink. Also, God wants His children and vessels of honour to be clean and fit for His use. A vast number of people need to experience the love, mercy and goodness of God through His children for the expansion of His kingdom. In order to qualify to be a worthy vessel, we must hunger and desire God’s presence in our lives, dissociate ourselves from unholy associations, unholy behaviors, and seek God with a pure heart. We must allow God to work on our weaknesses through persistent prayer and study of the word of God. This will make us more and more like our Master and fit for His use.
PRAYER
Most Holy Father, please make me a worthy vessel of honour in your kingdom. Let my life bring honour and glory to your name. Amen.
BIBLE READINGS: 2 Timothy 2:20-21
OUN ELO FUN OLA
IRUGBIN NAA
“Bi enikeni ba we ara re mo kuro ninu iwonyi, oun yio je oun elo si ola ti a ya si oto ti o si ye fun ilo baale, ti a si ti pese sile fun ise rere gbogbo” 2 Tim 2:21
Oun Elo fun ola ni Olorun ma nlo lati fi rii wipe awon eniyan ni iriri oore re, ife, oju rere ati igbala. Olorun ma nfe lati lo awon oun elo ti o to ti a si ya si mimo lati se ise re. Gege bi eniyan ninu ile wa, a maa fe lati lo awon oun elo to mo lati fi jeun ati lati fi mu. Be naani Olorun se fe ki awon omo re wa ni mimo fun elo re. Opolopo eniyan Nilo lati ni iriri ife, anu ati oore Olorun nipase awon omo re, fun imugbooro ijoba re. Lati ye ni oun elo ola, a nilo lati pongbe fun iwa laaye olorun ninu aye wa, ki a yera fun awon ibasepo ti kii se mimo, awon iwa aimo, ki a si wa Olorun pelu okan ti o mo. Anilo lati je ki Olorun sise lori
ailera wa nipase adura ati kiko eko oro Olorun. Eyi yio mu wa jo Oluwa wa, ki a si ye fun ilo re.
ADURA
Baba mimo, jowo semi ni oun elo ola ni ijoba re. Jeki aye mi bu ola ati ogo fun oruko re. Amin.
BIBELI KIKA: 2 Timotiu 2:20-21